Deuteronomy 23:24 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
“Nígbà tí ẹ bá ń kọjá lọ ní ibi ọgbà àjàrà ẹlòmíràn, ẹ lè jẹ ìwọ̀nba èso àjàrà tí ó bá tẹ́ yín lọ́rùn, ṣugbọn ẹ kò gbọdọ̀ mú ẹyọkan lọ́wọ́ lọ.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nigbati iwọ ba wọ̀ inu ọgbà-àjara ẹnikeji rẹ lọ, iwọ le jẹ eso-àjara tẹrùn; ṣugbọn iwọ kò gbọdọ mú ọkan sinu ohunèlo rẹ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Bí o bá wọ inú ọgbà àjàrà aládùúgbò rẹ, o lè jẹ gbogbo èso àjàrà tí o bá fẹ́, ṣùgbọ́n má ṣe fi ìkankan sínú agbọ̀n rẹ.