Deuteronomy 24:22 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ẹ ranti pé ẹ ti jẹ́ ẹrú rí ní ilẹ̀ Ijipti, nítorí náà ni mo fi pàṣẹ fun yín láti ṣe èyí.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ki iwọ ki o si ma ranti pe iwọ ti ṣe ẹrú ni ilẹ Egipti: nitorina ni mo ṣe paṣẹ fun ọ lati ma ṣe nkan yi.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Rántí pé o ti jẹ́ àlejò ní Éjíbítì. Ìdí nìyí tí mo fi pa á láṣẹ fún ọ láti ṣe èyí.