Deuteronomy 26:7 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
A bá kígbe pe OLUWA Ọlọrun àwọn baba wa; ó gbọ́ ohùn wa, ó rí ìpọ́njú, ati ìṣẹ́, ati ìjìyà wa.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Awa si kepè OLUWA, Ọlọrun awọn baba wa, OLUWA si gbọ́ ohùn wa, o si wò ipọnju wa, ati lãlã wa, ati inira wa:
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nígbà náà ni a kégbe pe OLÚWA Ọlọ́run àwọn baba wa, OLÚWA sì gbọ́ ohùn wa, ó sì rí ìrora, làálàá àti ìnira wa.