Deuteronomy 27:16 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
“ ‘Ẹni ìfibú ni ẹnikẹ́ni tí ó bá tàbùkù baba tabi ìyá rẹ̀.’ “Gbogbo eniyan yóo sì dáhùn pé, ‘Amin.’
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Egún ni fun ẹniti kò fi baba rẹ̀ tabi iya rẹ̀ pè. Gbogbo enia yio si wipe, Amin.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
“Ègún ni fún ọkùnrin náà tí ó dójú ti baba tàbí ìyá rẹ̀” Nígbà náà ni gbogbo ènìyàn wọ̀nyí yóò wí pé, “Àmín!”