Deuteronomy 27:19 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
“ ‘Ẹni ìfibú ni ẹni tí ó bá yí ìdájọ́ òdodo tí ó tọ́ sí àlejò po, tabi ti aláìní baba, tabi ti opó.’ “Gbogbo eniyan yóo sì dáhùn pé, ‘Amin.’
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Egún ni fun ẹniti o nyi idajọ alejò po, ati ti alainibaba, ati ti opó. Gbogbo enia yio si wipe, Amin.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
“Ègún ni fún ọkùnrin náà tí ó yí ìdájọ́ po fún àléjò, aláìní baba tàbí opó” Nígbà náà ni gbogbo ènìyàn wọ̀nyí yóò wí pé, “Àmín!”