Deuteronomy 28:47 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Nítorí pé bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé Ọlọrun bukun yín, ẹ kọ̀, ẹ kò sìn ín pẹlu ayọ̀ ati inú dídùn.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitoriti iwọ kò fi àyọ sìn OLUWA Ọlọrun rẹ, ati inudidun, nitori ọ̀pọ ohun gbogbo:
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nítorí ìwọ kò sin OLÚWA Ọlọ́run rẹ ní ayọ̀ àti inú dídùn ní àkókò àlàáfíà.