Deuteronomy 29:12 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Kí gbogbo yín lè bá OLUWA Ọlọrun yín dá majẹmu lónìí,
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ki iwọ ki o le wọ̀ inu majẹmu OLUWA Ọlọrun rẹ, ati ibura rẹ̀, ti OLUWA Ọlọrun rẹ bá ọ ṣe li oni:
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
O dúró níhìn ín yìí kí o lè wọ inú májẹ̀mú pẹ̀lú OLÚWA Ọlọ́run rẹ, májẹ̀mú tí OLÚWA ń ṣe pẹ̀lú ù rẹ lónìí yìí àti tí óun dè pẹ̀lú ìbúra,