Deuteronomy 3:1 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
“Lẹ́yìn náà, a gbéra, a doríkọ ọ̀nà Baṣani. Ogu, ọba Baṣani, ati àwọn eniyan rẹ̀ bá ṣígun wá pàdé wa ní Edirei.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
NIGBANA li awa pada, a si lọ soke li ọ̀na Baṣani: Ogu ọba Baṣani si jade si wa, on ati gbogbo awọn enia rẹ̀, fun ìja ni Edrei.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Lẹ́yìn èyí ní a yípadà tí a sì kọrí sí ọ̀nà tí ó lọ sí Báṣánì, Ógù ọba Báṣánì àti gbogbo jagunjagun rẹ̀ ṣígun wá pàdé wa ní Édíréì.