Deuteronomy 3:19 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ṣugbọn àwọn aya yín ati àwọn ọmọ yín kéékèèké ati àwọn ẹran ọ̀sìn yín (mo mọ̀ pé wọ́n ti di pupọ nisinsinyii) yóo wà ninu àwọn ìlú tí mo ti fun yín
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Kìki awọn aya nyin, ati awọn ọmọ wẹ́wẹ nyin, ati ohunọ̀sin nyin, (emi mọ̀ pe ẹnyin lí ohunọ̀sin pupọ̀,) ni yio duro ni ilu nyin ti mo ti fi fun nyin;
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn ẹ̀yà a yín, àwọn ọmọ yín àti àwọn ohun ọ̀sìn in yín (Mo mọ̀ pé ẹ ti ní ohun ọ̀sìn púpọ̀) lè dúró ní àwọn ìlú tí mo fi fún un yín,