Deuteronomy 31:15 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
OLUWA fi ara hàn wọ́n ninu ọ̀wọ̀n ìkùukùu ninu àgọ́ náà. Ọ̀wọ̀n ìkùukùu náà wà ní ẹ̀bá ẹnu ọ̀nà àgọ́.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
OLUWA si yọ si wọn ninu agọ́ na ninu ọwọ̀n awọsanma: ọwọ̀n awọsanma na si duro loke ẹnu-ọ̀na agọ́ na.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nígbà náà ni OLÚWA farahàn níbi àgọ́ ní ọ̀wọ́ àwọsánmọ̀, àwọ-sánmọ̀ náà sì dúró sókè ẹnu ọ̀nà àgọ́.