Deuteronomy 32:11 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Bí ẹyẹ idì tií tú ìtẹ́ rẹ̀ ká, láti kọ́ àwọn ọmọ rẹ̀ bí à á tíí fò, tíí sì í na apá rẹ̀ láti hán wọn tí wọ́n bá fẹ́ já bọ́, bẹ́ẹ̀ ni OLUWA ń ṣe sí Israẹli.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Bi idì ti irú itẹ́ rẹ̀, ti iràbaba sori ọmọ rẹ̀, ti inà iyẹ́-apa rẹ̀, ti igbé wọn, ti ima gbé wọn lọ lori iyẹ́-apa rẹ̀:
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Bí idì ti íru ìtẹ́ rẹ̀ ti ó sì ń rábàbà sórí ọmọ rẹ̀, tí ó na ìyẹ́ apá rẹ̀ láti gbé wọn ki ó sì gbé wọn sórí ìyẹ́ apá rẹ̀.