Deuteronomy 32:13 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
“Ó fi wọ́n jọba lórí àwọn òkè ayé, ó sì fún wọn ní èso ilẹ̀ jẹ. Ó pèsè oyin fún wọn láti inú àpáta, ó sì mú kí igi olifi hù fún wọn lórí ilẹ̀ olókùúta.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
O mu u gùn ibi giga aiye, ki o le ma jẹ eso oko; o si jẹ ki o mu oyin lati inu apata wá, ati oróro lati inu okuta akọ wá;
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ó mú gun ibi gíga ayé ó sì fi èṣo oko bọ́ ọ. Ó sì jẹ́ kí ó mú oyin láti inú àpáta wá, àti òróró láti inú akọ òkúta wá,