Deuteronomy 32:16 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Wọ́n fi ìbọ̀rìṣà wọn sọ OLUWA di òjòwú; wọ́n fi ìwà burúkú wọn mú kí ibinu OLUWA wọn ru sókè.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nwọn fi oriṣa mu u jowú, ohun irira ni nwọn fi mu u binu.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Wọ́n sì fi jowú pẹ̀lú ọlọ́run àjèjì i wọn wọ́n sì mú un bínú pẹ̀lú àwọn òrìṣà a wọn.