Deuteronomy 32:19 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
“Nígbà tí OLUWA rí ohun tí àwọn ọmọ rẹ̀ ń ṣe, ó kọ̀ wọ́n sílẹ̀, nítorí pé, wọ́n mú un bínú.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
OLUWA si ri i, o si korira wọn, nitori ìwa-imunibinu awọn ọmọkunrin rẹ̀, ati ti awọn ọmọbinrin rẹ̀.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
OLÚWA sì rí èyí ó sì kọ̀ wọ́n, nítorí tí ó ti bínú nítori ìwà ìmúnibínú àwọn ọmọkùnrin àti ọmọbìnrin ìn rẹ.