Deuteronomy 32:22 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Nítorí iná ibinu mi ń jó, yóo sì jó títí dé isà òkú. Yóo jó ayé ati ohun gbogbo tí ń bẹ ninu rẹ̀ ní àjórun, tó fi mọ́ ìpìlẹ̀ àwọn òkè ńlá.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitoripe iná kan ràn ninu ibinu mi, yio si jó dé ipò-okú ni isalẹ, yio si run aiye pẹlu asunkún rẹ̀, yio si tinabọ ipilẹ awọn okenla.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nítorí pé iná kan ràn nínú ìbínú un mi, yóò sì jó dé ipò ikú ní ìṣàlẹ̀. Yóò sì run ayé àti ìkórè e rẹ̀ yóò sì tiná bọ ìpìlẹ̀ àwọn òkè ńlá.