Deuteronomy 32:24 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
N óo fi ebi pa wọ́n ní àpakú, iná yóo jó wọn ní àjórun, n óo sì fi àjàkálẹ̀ àrùn pa wọ́n run. N óo jẹ́ kí àwọn ẹranko burúkú pa wọ́n jẹ, n óo sì jẹ́ kí àwọn ejò olóró bù wọ́n ṣán.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ebi yio mu wọn gbẹ, oru gbigbona li a o fi run wọn, ati iparun kikorò; emi o si rán ehín ẹranko si wọn, pẹlu oró ohun ti nrakò ninu erupẹ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Èmi yóò mú wọn gbẹ, ooru gbígbóná àti ìparun kíkorò ni a ó fi run wọ́n. Pẹ̀lú oró ohun tí ń rákò nínú erùpẹ̀.