Deuteronomy 32:26 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ǹ bá wí pé kí n fọ́n wọn káàkiri, kí ẹnikẹ́ni má tilẹ̀ ranti wọn mọ́,
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Mo wipe, Emi o tu wọn ká patapata, emi o si mu iranti wọn dá kuro ninu awọn enia:
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Mo ní èmi yóò tú wọn ká èmi yóò sì mú ìrántí i wọn dà kúró nínú àwọn ènìyàn,