Deuteronomy 32:27 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
ti àwọn ọ̀tá wọn ni mo rò, nítorí pé, ọ̀tọ̀ ni ohun tí wọn yóo máa wí kiri. Wọn yóo máa wí pé, “Àwa ni a ṣẹgun wọn, kìí ṣe OLUWA ló ṣe é rárá.” ’
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Bikoṣepe bi mo ti bẹ̀ru ibinu ọtá, ki awọn ọtá wọn ki o má ba ṣe alaimọ̀, ati ki nwọn ki o má ba wipe, Ọwọ́ wa leke ni, ki isi ṣe OLUWA li o ṣe gbogbo eyi.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
nítorí bí mo ti bẹ̀rù ìbínú ọ̀ta, kí àwọn ọ̀ta a wọn kí ó má ba à wí pé, ‘Ọwọ́ ọ wa lékè ni; kì í sì í ṣe OLÚWA ni ó ṣe gbogbo èyí.’ ”