Deuteronomy 32:28 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
“Nítorí pé aláìlérò orílẹ̀-èdè ni Israẹli, òye kò sì yé wọn rárá.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitori orilẹ-ède ti kò ní ìmọ ni nwọn, bẹ̃ni kò sí òye ninu wọn.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Wọ́n jẹ́ orílẹ̀ èdè tí kò ní ìmọ̀, bẹ́ẹ̀ ni kò sí òye nínú un wọn.