Deuteronomy 32:31 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Nítorí pé, àwọn ọ̀tá wọn pàápàá mọ̀ pé, Ọlọrun, aláàbò Israẹli, kì í ṣe ẹgbẹ́ àwọn oriṣa wọn.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitoripe apata wọn kò dabi Apata wa, ani awọn ọtá wa tikalawọn ni nṣe onidajọ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nítorí pé àpáta wọn kò dàbí Àpáta wa, àní àwọn ọ̀ta wa tìkálára wọn ń ṣe onídàájọ́.