Deuteronomy 32:34 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
“Èmi OLUWA kò gbàgbé ohun tí àwọn ọ̀tá wọn ṣe, ṣebí gbogbo rẹ̀ wà ní àkọsílẹ̀ lọ́dọ̀ mi?
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Eyi ki a tojọ sọdọ mi ni ile iṣura, ti a si fi èdidi dì ninu iṣura mi?
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
“Èmi kò to èyí jọ ní ìpamọ́ èmi kò sì fi èdìdì dìí ní ìṣúra à mi?