Deuteronomy 32:35 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Èmi OLUWA ni ẹlẹ́san, n óo sì gbẹ̀san, nítorí ọjọ́ ń bọ̀, tí àwọn pàápàá yóo yọ̀ ṣubú. Ọjọ́ ìdààmú wọn kù sí dẹ̀dẹ̀, ọjọ́ ìparun wọn sì ń bọ̀ kíákíá.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ti emi ni igbẹsan, ati ẹsan, li akokò ti ẹsẹ̀ wọn yio yọ́: nitoriti ọjọ́ idamu wọn sunmọtosi, ohun ti o si mbọ̀ wa bá wọn nyára wá.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ti èmi ni láti gbẹ̀san; Èmi yóò san án fún wọn ní àkókò tí ẹ̀sẹ̀ wọn yóò yọ; ọjọ́ ìdàmú wọn sún mọ́ etílé ohun tí ó sì ń bọ̀ wá bá wọn yára bọ̀.”