Deuteronomy 32:37 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Nígbà náà ni yóo bi wọ́n pé, ‘Níbo ni àwọn oriṣa yin wà, ati àpáta tí ẹ fi ṣe ààbò yin?
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
On o si wipe, Nibo li oriṣa wọn gbé wà, apata ti nwọn gbẹkẹle:
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Yóò wí pé: “Òrìṣà a wọn dà báyìí, àpáta tí wọ́n fi ṣe ìgbẹ́kẹ̀lé e wọn,