Deuteronomy 32:38 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ṣebí àwọn ni ẹ fún ní ọ̀rá ẹran ìrúbọ yín, àwọn ni ẹ sì rú ẹbọ ohun mímu yín sí? Kí wọ́n dìde, kí wọ́n ràn yín lọ́wọ́ nisinsinyii, kí wọ́n sì dáàbò bò yín.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ti o ti jẹ ọrá ẹbọ wọn, ti o ti mu ọti-waini ẹbọ ohunmimu wọn? jẹ ki nwọn dide ki nwọn si ràn nyin lọwọ, ki nwọn ṣe àbo nyin.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
ọlọ́run tí ó jẹ ara ẹbọ wọn tí ó ti mu ọtí i wáìnì ẹbọ ohun mímu wọn? Jẹ́ kí wọn dìde láti gbà wọ́n! Jẹ́ kí wọn ṣe ààbò fún un yín!