Deuteronomy 32:41 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Nígbà tí mo bá pọ́n idà mi, tí ó ń kọ yànrànyànràn, n óo fà á yọ láti fi ṣe ẹ̀tọ́. N óo gbẹ̀san lára àwọn ọ̀tá mi, n óo sì jẹ àwọn tí wọ́n kórìíra mi níyà.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Bi mo ba si pọ́n idà didan mi, ti mo ba si fi ọwọ́ mi lé idajọ; emi o san ẹsan fun awọn ọtá mi, emi o radi i fun awọn ti o korira mi.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
nígbà tí mo bá pọ́n idà dídán mi àti tí mo bá sì fi ọwọ́ mi lé ìdájọ́, Èmi yóò san ẹ̀san fún àwọn ọ̀tá mi Èmi kò sì san fún àwọn tí ó kórìíra à mi.