Deuteronomy 32:9 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Nítorí pé ìpín OLUWA ni àwọn eniyan rẹ̀, ó yan àwọn ọmọ Jakọbu ní ohun ìní fún ara rẹ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitoripe ipín ti OLUWA li awọn enia rẹ̀; Jakobu ni ipín iní rẹ̀.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nítorí ìpín OLÚWA ni àwọn ènìyàn an rẹ̀, Jákọ́bù ni ìpín ìní i rẹ̀.