Deuteronomy 33:10 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Wọn óo kọ́ ilé Jakọbu ní ìlànà rẹ, wọn óo sì kọ́ àwọn ọmọ Israẹli ní òfin rẹ. Àwọn ni wọn óo máa sun turari níbi ẹbọ rẹ, wọn óo sì máa rú ẹbọ sísun lórí pẹpẹ rẹ.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nwọn o ma kọ́ Jakobu ni idajọ rẹ, ati Israeli li ofin rẹ: nwọn o ma mú turari wá siwaju rẹ, ati ọ̀tọtọ ẹbọ sisun sori pẹpẹ rẹ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ó kọ́ Jákọ́bù ní ìdájọ́ rẹ̀ àti Ísírẹ́lì ní òfin rẹ̀. Ó mú tùràrí wá ṣíwájú rẹ̀ àti ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ ẹbọ sísun sórí i pẹpẹ rẹ̀.