Deuteronomy 33:13 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ó súre fún ẹ̀yà Josẹfu pé: “Kí OLUWA rọ òjò ibukun sórí ilẹ̀ wọn, kí ó sì bu omi rin ín láti abẹ́ ilẹ̀ wá.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ati niti Josefu o wipe, Ibukún OLUWA ni ilẹ rẹ̀, fun ohun iyebiye ọrun, fun ìri, ati fun ibú ti o ba nisalẹ,
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ní ti Jóṣẹ́fù ó wí pé: “Kí OLÚWA bùkún ilẹ̀ rẹ, fún ohun iyebíye láti ọ̀run pẹ̀lú ìrì àti ibú tí ó ń bẹ níṣàlẹ̀;