Deuteronomy 33:14 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Kí OLUWA pèsè ọpọlọpọ èso sórí ilẹ̀ wọn, kí ó sì kún fún àwọn èso tí ó dára jùlọ láti ìgbà dé ìgbà.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ati fun eso iyebiye ti õrùn múwa, ati fun ohun iyebiye ti ndàgba li oṣoṣù,
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
àti fún èso iyebíye tí ọ̀run mú wá àti ti ohun iyebíye tí ń dàgbà ní oṣooṣù;