Deuteronomy 33:16 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Kí ilẹ̀ wọn kún fún oríṣìíríṣìí àwọn ohun tí ó dára, pẹlu ibukun láti ọ̀dọ̀ ẹni tí ń gbé inú pápá tí ń jó. Kí ó wá sórí Josẹfu, àní, sórí ẹni tó jẹ́ aṣiwaju fún àwọn arakunrin rẹ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ati fun ohun iyebiye aiye ati ẹkún rẹ̀, ati fun ifẹ́ inurere ẹniti o gbé inu igbẹ́: jẹ ki ibukún ki o wá si ori Josefu, ati si atari ẹniti a yàsọtọ lãrin awọn arakunrin rẹ̀.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Pẹ̀lú ohun iyebíye ayé àti ẹ̀kún un rẹ̀ àti fún ìfẹ́ ẹni tí ó ń gbé inú igbó. Jẹ́ kí gbogbo èyí sinmi lé orí Jósẹ́fù, lórí àtàrí ẹni tí ó yàtọ̀ láàrin àwọn arákùnrin rẹ̀.