Deuteronomy 33:24 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ìre tí ó sú fún ẹ̀yà Aṣeri ni pé: “Ibukun ẹ̀yà Aṣeri ta gbogbo ibukun ẹ̀yà yòókù yọ, àyànfẹ́ ni yóo jẹ́ láàrin àwọn arakunrin rẹ̀, ilẹ̀ rẹ̀ yóo sì kún fún òróró olifi.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ati niti Aṣeri o wipe, Ibukún ọmọ niti Aṣeri; ki on ki o si jẹ́ itẹwọgba fun awọn arakunrin rẹ̀, ki on ki o si ma rì ẹsẹ̀ rẹ̀ sinu oróro.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ní ti Áṣérì ó wí pé: “Ìbùkún ọmọ ni ti Áṣérì; jẹ́ kí ó rí ojú rere láti ọ̀dọ̀ àwọn arákùnrin rẹ̀ kí ó sì ri ẹṣẹ̀ rẹ̀ sínú òróró.