Deuteronomy 33:3 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ọlọrun fẹ́ràn àwọn eniyan rẹ̀, gbogbo àwọn tí a yà sọ́tọ̀ fún un wà lọ́wọ́ rẹ̀, nítorí náà ni wọ́n ṣe ń tẹ̀lé ọ̀nà rẹ̀, tí wọ́n sì ń gba àṣẹ lọ́dọ̀ rẹ̀,
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitõtọ, o fẹ́ awọn enia na; gbogbo awọn enia mimọ́ rẹ̀ wà li ọwọ́ rẹ. Nwọn si joko li ẹsẹ̀ rẹ; olukuluku ni yio gbà ninu ọ̀rọ rẹ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nítòótọ́, ó fẹ́ràn àwọn ènìyàn an rẹ̀, gbogbo àwọn ènìyàn mímọ́ wà ní ọwọ́ rẹ̀. Ní ẹṣẹ̀ rẹ̀ ni wọ́n ti foríbalẹ̀, àti lọ́dọ̀ rẹ̀ ni wọ́n ti ń gba ọ̀rọ̀,