Deuteronomy 33:5 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Bẹ́ẹ̀ ni OLUWA ṣe di ọba ní Jeṣuruni, nígbà tí gbogbo àwọn olórí péjọ, àní, gbogbo àwọn olórí ninu ẹ̀yà Israẹli.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
O si jẹ́ ọba ni Jeṣuruni, nigbati olori awọn enia, awọn ẹ̀ya Israeli pejọ pọ̀.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Òun ni ọba lórí Jéṣúrúnì ní ìgbà tí olórí àwọn ènìyàn péjọ pọ̀, pẹ̀lú àwọn ẹ̀yà Ísírẹ́lì