Deuteronomy 33:7 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ó súre fún ẹ̀yà Juda pé: “OLUWA, gbọ́ igbe ẹ̀yà Juda, nígbà tí wọ́n bá pè fún ìrànwọ́, sì kó wọn pada sọ́dọ̀ àwọn eniyan wọn. Fi ọwọ́ ara rẹ jà fún wọn, sì ràn wọ́n lọ́wọ́ láti borí àwọn ọ̀tá wọn.”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Eyi si ni ti Judah: o si wipe, OLUWA, gbọ́ ohùn Judah, ki o si mú u tọ̀ awọn enia rẹ̀ wá: ki ọwọ́ rẹ̀ ki o to fun u; ki iwọ ki o si ṣe iranlọwọ fun u lọwọ awọn ọtá rẹ̀.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Èyí ni ohun tí ó sọ nípa Júdà: “OLÚWA gbọ́ ohùn Júdà kí o sì mú tọ àwọn ènìyàn rẹ̀ wá. Kí ọwọ́ rẹ̀ kí ó tó fún un, kí ó sì ṣe ìrànlọ́wọ́ fún lọ́wọ́ àwọn ọ̀ta rẹ̀!”