Deuteronomy 4:3 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ẹ̀yin náà ti fi ojú yín rí ohun tí OLUWA ṣe ní Baali Peori, nítorí pé, OLUWA Ọlọrun yín pa gbogbo àwọn tí wọn ń bọ oriṣa Baali tí ó wà ní Peori run kúrò láàrin yín.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Oju nyin ti ri ohun ti OLUWA ṣe nitori Baali-peori: nitoripe gbogbo awọn ọkunrin ti o tẹlé Baali-peori lẹhin, OLUWA Ọlọrun rẹ ti run wọn kuro lãrin rẹ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ẹ ti fi ojú ara yín rí ohun tí OLÚWA ṣe ní Báálí-Péórì. OLÚWA Ọlọ́run yín run gbogbo àwọn tí ó tẹ̀lé òrìṣà Báálì ti Péórì kúrò ní àárin yín.