Deuteronomy 4:7 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
“Ǹjẹ́, orílẹ̀-èdè ńlá wo ni ó tún wà, tí ó ní oriṣa tí ó súnmọ́ ọn gẹ́gẹ́ bí OLUWA Ọlọrun tií súnmọ́ wa nígbàkúùgbà tí a bá pè é?
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitori orilẹ-ède nla wo li o wà, ti o ní Ọlọrun sunmọ wọn to, bi OLUWA Ọlọrun wa ti ri ninu ohun gbogbo ti awa kepè e si?
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Orílẹ̀ èdè olókìkí wo ni Ọlọ́run wọn tún súnmọ́ wọn, bí OLÚWA Ọlọ́run wa ti súnmọ́ wa nígbàkugbà tí a bá ń képè é?