Deuteronomy 5:26 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Nítorí pé ninu gbogbo ẹ̀dá alààyè, ta ni ó tíì gbọ́ ohùn OLUWA Ọlọrun alààyè rí láti inú iná, gẹ́gẹ́ bí àwa ti gbọ́ ọ yìí, tí ó sì wà láàyè?
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitoripe tani mbẹ ninu gbogbo araiye ti o ti igbọ́ ohùn Ọlọrun alãye ti nsọ̀rọ lati ãrin iná wá, bi awa ti gbọ́, ti o si wà lãye?
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ta ni nínú ẹlẹ́ran ara tí ó ti gbọ́ ohun OLÚWA Ọlọ́run láti inú iná rí, bí àwa ti gbọ́ ọ, tí a sì wà láyé?