Deuteronomy 5:27 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ìwọ Mose, súnmọ́ ọ̀dọ̀ rẹ̀, kí o sì gbọ́ gbogbo ohun tí OLUWA Ọlọrun yóo sọ, kí o wá sọ fún wa, a óo sì ṣe é.’
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Iwọ sunmọtosi, ki o si gbọ́ gbogbo eyiti OLUWA Ọlọrun wa yio wi: ki iwọ ki o sọ fun wa gbogbo ohun ti OLUWA Ọlọrun wa yio sọ fun ọ: awa o si gbọ́, awa o si ṣe e.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Súnmọ́ tòsí ibẹ̀ kí o sì gbọ́ gbogbo ohun tí OLÚWA Ọlọ́run wa yóò sọ, nígbà náà sọ ohunkóhun tí OLÚWA Ọlọ́run wa sọ fún ọ fún wa. A ó sì fetísílẹ̀, a ó sì gbọ́ran.”