Deuteronomy 7:17 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
“Bí ẹ bá rò ní ọkàn yín pé àwọn eniyan wọnyi pọ̀ jù yín lọ, ati pé báwo ni ẹ ṣe lè lé wọn jáde,
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Bi iwọ ba wi li ọkàn rẹ pe, Awọn orilẹ-ède wọnyi pọ̀ jù mi lọ; bawo li emi o ṣe le lé wọn jade?
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ẹ lè máa rò láàrin ara yín pé, “Àwọn orílẹ̀ èdè yìí lágbára jù wá lọ. Báwo ni a o ṣe lé wọn jáde?”