Deuteronomy 8:4 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Aṣọ kò gbó mọ yín lára, bẹ́ẹ̀ ni ẹsẹ̀ yín kò wú, fún odidi ogoji ọdún yìí.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Aṣọ rẹ kò gbó mọ́ ọ lara, bẹ̃li ẹsẹ̀ rẹ kò wú, lati ogoji ọdún yi wá.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Aṣọ yín kò gbó mọ́ ọ yín lọ́rùn bẹ́ẹ̀ ní ẹṣẹ̀ yín kò sì wú, ní ogójì ọdún náà.