Deuteronomy 9:20 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Inú bí OLUWA sí Aaroni tóbẹ́ẹ̀ tí OLUWA fi ṣetán láti pa á run, ṣugbọn mo gbadura fún Aaroni nígbà náà.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
OLUWA si binu si Aaroni gidigidi ti iba fi pa a run: emi si gbadura fun Aaroni nigbana pẹlu.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Inú sì bí OLÚWA sí Árónì láti pa á run, nígbà náà ni mo tún gbàdúrà fún Árónì náà.