Ecclesiastes 1:7 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Inú òkun ni gbogbo odò tí ń ṣàn ń lọ, ṣugbọn òkun kò kún. Ibi tí àwọn odò ti ń ṣàn wá, ibẹ̀ ni wọ́n tún ṣàn pada lọ.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Odò gbogbo ni nṣan sinu okun; ṣugbọn okun kò kún, nibiti awọn odò ti nṣàn wá, nibẹ ni nwọn si tun pada lọ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Gbogbo odò ń sàn sí inú òkun síbẹ̀síbẹ̀ òkun kò kún. níbi tí àwọn odò ti wá, níbẹ̀ ni wọ́n tún padà sí