Ecclesiastes 10:17 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ilẹ̀ tí ọba rẹ̀ kì í bá ṣe ọmọ ẹrú ṣoríire! Tí àwọn olórí rẹ̀ ń ṣe àríyá ní àsìkò tí ó tọ́; tí wọn ń jẹ tí wọn ń mu kí wọn lè lágbára, ṣugbọn tí kì í ṣe fún ìmutípara.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ibukún ni fun ọ, iwọ ilẹ, nigbati ọba rẹ ba jẹ ọmọ ọlọlá, ti awọn ọmọ-alade rẹ njẹun li akoko ti o yẹ, fun ilera ti kì si iṣe fun ọti amupara!
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ìbùkún ni fún ọ, ìwọ ilẹ̀ èyí tí ọba rẹ̀ jẹ́ ọmọ ọlọ́lá, àti tí àwọn ọmọ aládé ń jẹun ní àsìkò tí ó yẹ, fún ìlera, tí kì í ṣe fún ìmọ̀tí para.