Ecclesiastes 10:6 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Wọ́n fi àwọn òmùgọ̀ sí ipò gíga, nígbà tí àwọn ọlọ́rọ̀ wà ní ipò tí ó rẹlẹ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
A gbe aṣiwère sipò ọlá, awọn ọlọrọ̀ si joko nipò ẹhin.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
A gbé aṣiwèrè sí ọ̀pọ̀ ipò tí ó ga jù lọ, nígbà tí ọlọ́rọ̀ gba àwọn àyè tí ó kéré jù lọ.