Ecclesiastes 11:1 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Gbin nǹkan ọ̀gbìn káàkiri lọpọlọpọ, o óo sì kórè ọpọlọpọ èso nígbà tó bá yá.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
FUN onjẹ rẹ si oju omi; nitoriti iwọ o ri i lẹhin ọjọ pupọ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Fún àkàrà rẹ ṣórí omi, nítorí lẹ́yìn ọjọ́ púpọ̀, ìwọ yóò ríi padà
Recommended Reading