Ecclesiastes 4:3 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ṣugbọn ti ẹni tí wọn kò tíì bí rárá, sàn ju ti àwọn mejeeji lọ, nítorí kò tíì rí iṣẹ́ ibi tí àwọn ọmọ aráyé ń ṣe.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitõtọ, ẹniti kò ti isi san jù awọn mejeji; ẹniti kò ti iri iṣẹ buburu ti a nṣe labẹ õrùn.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nítòótọ́, ẹni tí kò tí ì sí sàn ju àwọn méjèèjì lọ: ẹni tí kò tí ì rí iṣẹ́ búburú tí ó ń lọ ní abẹ́ oòrun.