Ecclesiastes 5:11 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Bí ọrọ̀ bá ti ń pọ̀ sí, bẹ́ẹ̀ ni iye àwọn tí yóo máa lò ó yóo máa pọ̀ sí i. Kò sì sí èrè tí ọlọ́rọ̀ yìí ní ju pé ó fi ojú rí ọrọ̀ rẹ̀ lọ.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nigbati ẹrù ba npọ̀ si i, awọn ti o si njẹ ẹ a ma pọ̀ si i: ore ki tilẹ ni fun ẹniti o ni i bikoṣepe ki nwọn ki o ma fi oju wọn wò o?
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Bí ẹrù bá ti ń pọ̀ síi náà ni àwọn tí ó ń jẹ ẹ́ yóò máa pọ̀ síi Èrè e kí ni wọ́n sì jẹ́ sí oní nǹkan bí kò se pé, kí ó máa mú inú ara rẹ dùn nípa rírí wọn?