Ecclesiastes 5:17 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ninu òkùnkùn, ati ìbànújẹ́ ni a ti ń lo ìgbésí ayé wa, pẹlu ọpọlọpọ ìyọnu, àìsàn ati ibinu.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Li ọjọ rẹ̀ gbogbo pẹlu, o njẹun li òkunkun, o si ni ibinujẹ pupọ ati àrun ati irora rẹ̀.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ó ń jẹ nínú òkùnkùn ní gbogbo ọjọ́ọ rẹ̀, pẹ̀lú iyè ríra tí ó ga, ìnira àti ìbínú.