Ecclesiastes 7:28 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
òun ni mò ń rò nígbà gbogbo, sibẹ, ó ṣì ń rú mi lójú: Láàrin ẹgbẹrun ọkunrin a lè rí ẹnìkan ṣoṣo tí ó jẹ́ eniyan rere, ṣugbọn ninu gbogbo àwọn obinrin, kò sí ẹnìkan.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ti ọkàn mi nwakiri sibẹ, ṣugbọn emi kò ri: ọkunrin kanṣoṣo ninu ẹgbẹrun ni mo ri; ṣugbọn obinrin kan ninu gbogbo awọn wọnni, emi kò ri.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nígbà tí mo sì ń wá a kiri ṣùgbọ́n tí n kò rí ì mo rí ọkùnrin tí ó dúró dáradára kan láàrin ẹgbẹ̀rún ṣùgbọ́n n kò rí obìnrin, kankan kí ó dúró láàrin gbogbo wọn.