Ecclesiastes 8:13 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ṣugbọn kò ní dára fún ẹni ibi, bẹ́ẹ̀ sì ni ọjọ́ rẹ̀ kò ní gùn bí òjìji, nítorí kò bẹ̀rù Ọlọrun.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ṣugbọn kì yio dara fun enia buburu, bẹ̃ni kì yio fa ọjọ rẹ̀ gun ti o dabi ojiji, nitoriti kò bẹ̀ru niwaju Ọlọrun.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ṣíbẹ̀ nítorí tí òsìkà kò bẹ̀rù Ọlọ́run, kò ní dára fún wọn, ọjọ́ wọn kò sì ní gùn bí òjìji.